Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dá ọba lóhùn pé, “Kò sí ẹni náà láyé yìí, tí ó lè sọ ohun tí kabiyesi fẹ́ kí á sọ, kò sí ọba ńlá tabi alágbára kankan tí ó tíì bèèrè irú nǹkan yìí lọ́wọ́ pidánpidán kan, tabi lọ́wọ́ àwọn aláfọ̀ṣẹ, tabi lọ́wọ́ àwọn ará Kalidea rí.

Ka pipe ipin Daniẹli 2

Wo Daniẹli 2:10 ni o tọ