Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 11:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí ó bá jọba, ìjọba rẹ̀ yóo pín sí ọ̀nà mẹrin. Àwọn ọba tí yóo jẹ lẹ́yìn rẹ̀ kò ní jẹ́ láti inú ìran rẹ̀, kò sì ní sí èyí tí yóo ní agbára tó o ninu wọn; nítorí a óo gba ìjọba rẹ̀, a óo sì fún àwọn ẹlòmíràn.

Ka pipe ipin Daniẹli 11

Wo Daniẹli 11:4 ni o tọ