Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 11:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò ní náání oriṣa tí àwọn baba rẹ̀ ń sìn, kò sì ní bìkítà fún èyí tí àwọn obinrin fẹ́ràn; kò ní bìkítà fún oriṣa kankan, nítorí pé yóo gbé ara rẹ̀ ga ju gbogbo wọn lọ.

Ka pipe ipin Daniẹli 11

Wo Daniẹli 11:37 ni o tọ