Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 11:30 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí pé, àwọn ọmọ ogun Kitimu tí wọ́n wà ninu ọkọ̀ ojú omi yóo gbógun tì í.“Ẹ̀rù yóo bà á, yóo sì sá pada, yóo fi ibinu ńlá gbógun ti majẹmu mímọ́ Ọlọrun ati Israẹli, yóo sì máa tẹ̀lé ìmọ̀ràn àwọn tí wọ́n ti kọ majẹmu náà sílẹ̀.

Ka pipe ipin Daniẹli 11

Wo Daniẹli 11:30 ni o tọ