Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 11:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii, n óo fi òtítọ́ hàn ọ́.”Angẹli náà tún ní, “Àwọn ọba mẹta ni yóo jẹ sí i ní Pasia; ẹkẹrin yóo ní ọrọ̀ pupọ ju gbogbo àwọn yòókù lọ; nígbà tí ó bá sì ti ipa ọrọ̀ rẹ̀ di alágbára tán, yóo ti gbogbo eniyan nídìí láti bá ìjọba Giriki jagun.

Ka pipe ipin Daniẹli 11

Wo Daniẹli 11:2 ni o tọ