Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 11:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, yóo bá àwọn orílẹ̀-èdè ati àwọn ilẹ̀ tí ó wà ní etíkun jà, yóo sì ṣẹgun ọpọlọpọ wọn. Ṣugbọn olórí-ogun kan yóo ṣẹgun rẹ̀, yóo sì pa òun náà run.

Ka pipe ipin Daniẹli 11

Wo Daniẹli 11:18 ni o tọ