Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 11:13 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí pé ọba Siria yóo tún pada lọ, yóo kó ogun jọ, tí yóo pọ̀ ju ti iṣaaju lọ. Nígbà tí ó bá yá, lẹ́yìn ọpọlọpọ ọdún, yóo pada wá pẹlu ikọ̀ ọmọ ogun tí ó lágbára, pẹlu ọpọlọpọ ihamọra ati ohun ìjà.

Ka pipe ipin Daniẹli 11

Wo Daniẹli 11:13 ni o tọ