Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 10:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bi mí pé, “Ǹjẹ́ o mọ ìdí tí mo fi tọ̀ ọ́ wá? Nisinsinyii n óo pada lọ bá aláṣẹ ìjọba Pasia jà, tí mo bá bá a jà tán, aláṣẹ ìjọba Giriki yóo wá.

Ka pipe ipin Daniẹli 10

Wo Daniẹli 10:20 ni o tọ