Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 10:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá dá mi lọ́kàn le, ó ní, “Má bẹ̀rù, Daniẹli, nítorí láti ọjọ́ tí o ti pinnu láti mòye, tí o sì rẹ ara rẹ sílẹ̀ níwájú Ọlọrun rẹ, gbogbo ohun tí ò ń bèèrè ni a ti gbọ́, adura rẹ ni mo sì wá dáhùn.

Ka pipe ipin Daniẹli 10

Wo Daniẹli 10:12 ni o tọ