Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹta tí Kirusi jọba ní Pasia, Daniẹli, (tí à ń pè ní Beteṣasari) rí ìran kan. Òtítọ́ ni ìran náà, ó ṣòro láti túmọ̀, ṣugbọn a la ìran náà ati ìtumọ̀ rẹ̀ yé Daniẹli.

Ka pipe ipin Daniẹli 10

Wo Daniẹli 10:1 ni o tọ