Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA jẹ́ kí ọwọ́ rẹ̀ tẹ Jehoiakimu ọba Juda. Nebukadinesari kó ninu àwọn ohun èlò ilé Ọlọrun lọ sí ilẹ̀ Ṣinari, ó sì kó wọn sinu ilé ìṣúra tí ó wà ninu ilé oriṣa rẹ̀.

Ka pipe ipin Daniẹli 1

Wo Daniẹli 1:2 ni o tọ