Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, kí o wá fi wá wé àwọn tí wọn ń jẹ lára oúnjẹ àdídùn tí ọba ń jẹ, bí o bá ti wá rí àwa iranṣẹ rẹ sí ni kí o ṣe ṣe sí wa.”

Ka pipe ipin Daniẹli 1

Wo Daniẹli 1:13 ni o tọ