Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 1:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Aṣipenasi sọ fún Daniẹli, pé, ẹ̀rù ń ba òun, kí ọba tí ó ṣètò jíjẹ ati mímu Daniẹli ati àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ má baà lọ ṣe akiyesi pé Daniẹli rù ju àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ lọ, kí òun má baà fi ẹ̀mí òun wéwu lọ́dọ̀ ọba.

Ka pipe ipin Daniẹli 1

Wo Daniẹli 1:10 ni o tọ