Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 9:16 BIBELI MIMỌ (BM)

(Farao, ọba Ijipti ti gbógun ti ìlú Geseri ó sì dáná sun ún, ó pa gbogbo àwọn ará Kenaani tí wọn ń gbé inú rẹ̀. Ó fi ìlú náà ṣe ẹ̀bùn igbeyawo fún ọmọ rẹ̀ obinrin, nígbà tí ó fẹ́ Solomoni ọba.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 9

Wo Àwọn Ọba Kinni 9:16 ni o tọ