Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 7:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìtẹ́lẹ̀ mẹrin mẹrin ló wà ní orígun mẹrẹẹrin àwọn ìtẹ́dìí náà, ẹyọ kan náà ni wọ́n ṣe àwọn ìtẹ́lẹ̀ pẹlu ìtẹ́dìí yìí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 7

Wo Àwọn Ọba Kinni 7:34 ni o tọ