Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 7:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ṣe ọpọ́n orí òpó inú yàrá àbáwọlé náà bí ìtànná lílì, ó ga ní igbọnwọ mẹrin.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 7

Wo Àwọn Ọba Kinni 7:19 ni o tọ