Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 6:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n fi igi olifi gbẹ́ ẹ̀dá abìyẹ́ meji tí wọn ń pè ní Kerubu, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ga ní igbọnwọ mẹ́wàá, wọ́n kó wọn sinu Ibi-Mímọ́-Jùlọ náà.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 6

Wo Àwọn Ọba Kinni 6:23 ni o tọ