Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 6:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kọ́ ibi mímọ́ kan sí ọwọ́ ẹ̀yìn ilé ìsìn náà, inú ibi mímọ́ yìí ni wọ́n gbé Àpótí Ẹ̀rí OLUWA sí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 6

Wo Àwọn Ọba Kinni 6:19 ni o tọ