Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 22:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahabu wí fún Jehoṣafati pé, “Bí a ti ń lọ sí ojú ogun yìí, n óo paradà, kí ẹnikẹ́ni má baà dá mi mọ̀. Ṣugbọn ìwọ, wọ aṣọ oyè rẹ.” Ahabu, ọba Israẹli, bá paradà, ó sì lọ sójú ogun.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 22

Wo Àwọn Ọba Kinni 22:30 ni o tọ