Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 22:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nǹkan kan náà ni gbogbo àwọn wolii yòókù ń wí, gbogbo wọn ní kí Ahabu lọ gbógun ti Ramoti Gileadi, wọ́n ní OLUWA yóo fún un ní ìṣẹ́gun.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 22

Wo Àwọn Ọba Kinni 22:12 ni o tọ