Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 21:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesebẹli bá kọ ìwé ní orúkọ Ahabu, ó fi òǹtẹ̀ Ahabu tẹ̀ ẹ́, ó fi ranṣẹ sí àwọn àgbààgbà ati àwọn eniyan ńláńlá ní ìlú tí Naboti ń gbé.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 21

Wo Àwọn Ọba Kinni 21:8 ni o tọ