Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 19:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Elija dìde, ó jẹun, ó sì tún mu omi. Oúnjẹ náà sì fún un ní agbára láti rìn fún ogoji ọjọ́ tọ̀sán-tòru títí tí ó fi dé orí òkè Horebu, òkè Ọlọrun.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 19

Wo Àwọn Ọba Kinni 19:8 ni o tọ