Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 19:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá dáhùn pé, “Mò ń jowú nítorí OLUWA, Ọlọrun àwọn ọmọ ogun, nítorí pé àwọn ọmọ Israẹli ti da majẹmu rẹ̀, wọ́n ti wó pẹpẹ rẹ̀ lulẹ̀, wọ́n sì ti fi idà pa àwọn wolii rẹ̀. Èmi nìkan ṣoṣo, ni mo ṣẹ́kù, wọ́n sì fẹ́ gba ẹ̀mí èmi náà.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 19

Wo Àwọn Ọba Kinni 19:14 ni o tọ