Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 19:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ náà, iná ńlá kan bẹ̀rẹ̀ sí jó. Ṣugbọn OLUWA kò sí ninu iná náà. Lẹ́yìn iná náà, ohùn kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ kan rọra sọ̀rọ̀ jẹ́ẹ́jẹ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 19

Wo Àwọn Ọba Kinni 19:12 ni o tọ