Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 18:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Láìpẹ́, ìkùukùu bo gbogbo ojú ọ̀run, afẹ́fẹ́ bẹ̀rẹ̀ sí fẹ́, òjò ńlá sì bẹ̀rẹ̀ sí rọ̀. Ahabu kó sinu kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀, ó sì pada lọ sí Jesireeli.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 18

Wo Àwọn Ọba Kinni 18:45 ni o tọ