Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 14:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Rehoboamu bá ṣe apata idẹ dípò wọn. Ó sì fi àwọn olórí ẹ̀ṣọ́ tí ń ṣọ́ ẹnu ọ̀nà ààfin ọba ṣe alabojuto wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 14

Wo Àwọn Ọba Kinni 14:27 ni o tọ