Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 13:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wolii àgbàlagbà náà gbọ́, ó ní, “Wolii tí ó ṣàìgbọràn sí ọ̀rọ̀ OLUWA ni. Nítorí náà ni OLUWA fi rán kinniun sí i, pé kí ó pa á, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti kìlọ̀ fún un tẹ́lẹ̀.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 13

Wo Àwọn Ọba Kinni 13:26 ni o tọ