Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 12:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeroboamu ati gbogbo àwọn eniyan náà bá pada wá sọ́dọ̀ Rehoboamu ní ọjọ́ kẹta, gẹ́gẹ́ bí ó ti pàṣẹ fún wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 12

Wo Àwọn Ọba Kinni 12:12 ni o tọ