Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 11:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú bí OLUWA sí Solomoni, nítorí pé, ọkàn rẹ̀ ti yipada kúrò lọ́dọ̀ OLUWA Ọlọrun Israẹli tí ó fara hàn án nígbà meji,

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 11

Wo Àwọn Ọba Kinni 11:9 ni o tọ