Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 11:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí Dafidi ti ṣẹgun Hadadeseri ọba, tí ó sì ti pa àwọn ará Siria tí wọ́n wà lẹ́yìn rẹ̀, Resoni di olórí àwọn ìgárá ọlọ́ṣà kan tí wọ́n kó ara wọn jọ, tí wọn ń gbé Damasku. Àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ bá fi jọba ní Damasku.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 11

Wo Àwọn Ọba Kinni 11:24 ni o tọ