Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Kinni 1:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò yìí, Dafidi ọba ti di arúgbó. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé aṣọ tí ó nípọn ni wọ́n fi ń bò ó, òtútù a tún máa mú un.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 1

Wo Àwọn Ọba Kinni 1:1 ni o tọ