Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 9:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ìdílé Ahabu ni yóo ṣègbé, n óo sì pa gbogbo àwọn ọmọkunrin tí wọ́n wà ninu ìdílé náà, ati ẹrú ati ọmọ.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 9

Wo Àwọn Ọba Keji 9:8 ni o tọ