Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 9:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehu bá ké sí wọn, ó ni, “Ẹ Jù ú sílẹ̀.” Wọ́n bá ju Jesebẹli sí ìsàlẹ̀, ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sì ta sí ara ògiri ati sí ara àwọn ẹṣin, àwọn ẹṣin Jehu sì tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀ kọjá.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 9

Wo Àwọn Ọba Keji 9:33 ni o tọ