Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 9:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehu fi gbogbo agbára ta ọfà rẹ̀, ó bá Joramu lẹ́yìn, ó wọ inú ọkàn rẹ̀ lọ, Joramu sì kú sinu kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 9

Wo Àwọn Ọba Keji 9:24 ni o tọ