Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 9:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehu gun kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀, ó lọ sí Jesireeli nítorí ibẹ̀ ni Joramu ọba wà, Ahasaya, ọba Juda sì wá bẹ̀ ẹ́ wò níbẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 9

Wo Àwọn Ọba Keji 9:16 ni o tọ