Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 8:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀nà ìdílé Ahabu ọba ni Ahasaya tẹ̀ sí, ó sì ṣe burúkú níwájú OLUWA, bí ìdílé Ahabu ti ṣe; nítorí pé àna ló jẹ́ fún Ahabu.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 8

Wo Àwọn Ọba Keji 8:27 ni o tọ