Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 7:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Samaria sì tú jáde láti lọ kó ìkógun ní ibùdó ogun àwọn ará Siria. Gẹ́gẹ́ bí ohun tí OLUWA ti sọ, wọ́n ta òṣùnwọ̀n ìyẹ̀fun kíkúnná kan ní ìwọ̀n ṣekeli kan.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 7

Wo Àwọn Ọba Keji 7:16 ni o tọ