Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 7:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliṣa dáhùn pé, “Gbọ́ ọ̀rọ̀ OLUWA, ní àkókò yìí lọ́la, ní ẹnubodè Samaria, àwọn eniyan yóo ra òṣùnwọ̀n ìyẹ̀fun kíkúnná kan, tabi òṣùnwọ̀n ọkà baali meji ní ìwọ̀n ṣekeli kan.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 7

Wo Àwọn Ọba Keji 7:1 ni o tọ