Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 6:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní kété tí wọ́n wọ Samaria, Eliṣa gbadura pé kí OLUWA ṣí wọn lójú kí wọ́n lè ríran. OLUWA sì ṣí wọn lójú, wọ́n rí i pé ààrin Samaria ni àwọn wà.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 6

Wo Àwọn Ọba Keji 6:20 ni o tọ