Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 6:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ará Siria gbìyànjú láti mú un, ó gbadura pé kí OLUWA jọ̀wọ́ fọ́ àwọn ọkunrin náà lójú. OLUWA sì fọ́ wọn lójú gẹ́gẹ́ bí adura Eliṣa.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 6

Wo Àwọn Ọba Keji 6:18 ni o tọ