Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 6:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkàn ọba Siria kò balẹ̀ nítorí ọ̀rọ̀ yìí, nítorí náà, ó pe gbogbo àwọn olórí ogun rẹ̀ jọ, ó sì bi wọ́n pé, “Ta ló ń tú àṣírí wa fún ọba Israẹli ninu yín?”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 6

Wo Àwọn Ọba Keji 6:11 ni o tọ