Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 5:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọba Israẹli ka ìwé náà ó fa aṣọ rẹ̀ ya láti fi ìbẹ̀rù rẹ̀ hàn, ó sì wí pé, “Èmi ha í ṣe Ọlọrun tí ó ní agbára ikú ati ìyè bí, tí ọba Siria fi rò wí pé mo lè wo eniyan sàn kúrò ninu ẹ̀tẹ̀? Èyí fi hàn pé ó ń wá ìjà ni.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 5

Wo Àwọn Ọba Keji 5:7 ni o tọ