Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 5:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n dé orí òkè tí Eliṣa ń gbé, Gehasi gba àwọn ẹrù náà lórí wọn, ó gbé wọn sinu ilé, ó sì dá àwọn iranṣẹ Naamani pada.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 5

Wo Àwọn Ọba Keji 5:24 ni o tọ