Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 5:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Naamani bá ní, “Jọ̀wọ́ fún mi ní ààyè láti bu erùpẹ̀ ẹrù kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ meji lọ sílé nítorí láti òní lọ, iranṣẹ rẹ kì yóo rúbọ sí ọlọrun mìíràn bíkòṣe OLUWA.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 5

Wo Àwọn Ọba Keji 5:17 ni o tọ