Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 5:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé àwọn odò Abana ati odò Faripari tí wọ́n wà ní Damasku kò dára ju gbogbo àwọn odò tí wọ́n wà ní Israẹli lọ ni? Ṣebí mo lè wẹ̀ ninu wọn kí n sì mọ́!” Ó bá yipada, ó ń bínú lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 5

Wo Àwọn Ọba Keji 5:12 ni o tọ