Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 4:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliṣa dé sí Giligali nígbà tí ìyàn wà ní ilẹ̀ náà. Bí àwọn ọmọ wolii ti jókòó níwájú rẹ̀, ó sọ fún àwọn iranṣẹ rẹ̀, ó ní, “Ẹ gbé ìkòkò ńlá léná kí ẹ sì se àsáró fún àwọn ọmọ wolii.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 4

Wo Àwọn Ọba Keji 4:38 ni o tọ