Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 4:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó wí fún Gehasi pé kí ó pe obinrin ará Ṣunemu náà wá, Gehasi bá pè é. Nígbà tí obinrin náà dé, Eliṣa wí fún un pé kí ó gba ọmọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 4

Wo Àwọn Ọba Keji 4:36 ni o tọ