Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 4:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó nà gbalaja lé ọmọ náà lórí, ó fẹnu kò ó lẹ́nu, ó fojú kò ó lójú, ó sì gbé ọwọ́ lé ọwọ́ rẹ̀. Bí ó sì ti nà lé ọmọ náà, ara ọmọ náà bẹ̀rẹ̀ sí lọ́ wọ́ọ́rọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 4

Wo Àwọn Ọba Keji 4:34 ni o tọ