Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 4:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliṣa bá sọ fún Gehasi pé, “Ṣe gírí, kí o mú ọ̀pá mi lọ́wọ́, kí o sì máa lọ. Bí o bá pàdé ẹnikẹ́ni lọ́nà, má ṣe kí i, bí ẹnikẹ́ni bá kí ọ, má dáhùn.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 4

Wo Àwọn Ọba Keji 4:29 ni o tọ