Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Ọba Keji 3:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kígbe pé, “Ẹ wo ẹ̀jẹ̀! Dájúdájú àwọn ọba mẹtẹẹta wọnyi ti bá ara wọn jà, wọ́n sì ti pa ara wọn, ẹ jẹ́ kí á lọ kó ìkógun ninu ibùdó-ogun wọn.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 3

Wo Àwọn Ọba Keji 3:23 ni o tọ